One year in memory of MAMA OLOSE
Man is mortal but the love for them is immortal. Though you are not present here with all of us but your memory is stored on our mind.
We dreamt of living a long life together but the dreams had been shattered. Last year you left us here and went to heaven alone. We still think you are here by our side because we can feel you.
Mama Florence Mopelola Adenekan, we believe that it’s the body that dies not the soul. You’ll always be with us in our heart. There is nothing that wevcan do for you than praying. May God bless your soul!
Ejire oyila oba omo
Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún.
Ẹdúnjobí
Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi
Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà,
Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa;
Ó salákìísà donígba aṣọ.
Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá,
Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ.
Wínrinwínrin lójú orogún
Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀.
Omo Afotamodi K'ogun ma wolu
Omo Ode gege bii Omo Ooni
Omo Oluwo Asape Ola
Omooba Erinsiba Gugu
Awotuuru Jana
Omo oba Ayooledoye
Omo sakeke ni ona akuro
Omo Oluwo agbagba gooro
Omo olode agba-i-gbatan
Omo erun gba iwofa nruu danu
Aya Olowoboriaye
Ayawon nile Oba Igan labiya
Olola bi yaya
Omo ogan bi ojo.
May your soul continue to rest in peace...
Comments